[go: up one dir, main page]

JS 1 Yoruba L2 Exam 3RD Term

You might also like

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 5

DEEPER LIFE HIGH SCHOOL

THIRD TERM EXAMINATION 2020/2021 SESSION.


SUBJECT: YORUBA LANGUAGE L2 CLASS: J.S.1 TIME: 1hour 30mins
Answer all questions in sections A and question one plus any in section B

SECTION A:(Objective Test:Mu idahun ti o tona lati (Choose the option from) a-d).
1. Alifabeeti Yoruba je meloo (How many are the letters of the Yoruba alphabet?) (a)
Meedogbon (25) (b) Metadinlogbon(27) (c) Meedogun (15) (d) Marundinlogoji (35)
2. Faweli akoko ninu leta Yoruba ni (The first vowel of the alphabet of Yoruba is) __________
(a) e (b) i (c) a (d) u
3. Ewo ni ki i se leta Yoruba ninu awon wonyii (Which of these letters is not part of the Yoruba
alphabet)? (a) w (b) b (c) h (d) c
4. Konsonanti ti o gbeyin ninu alifabeeti Yoruba ni(The last consonant in Yoruba is ________
(a) S (b) W (c) Y (d) T
5. Faweli ti o gbeyin ni (The last vowel is) (a) e (b)i (c)u (d)a
6. Ewo ni ki i se leta ti Yoruba ninu awon wonyii (Which of these is not a letter in Yoruba
alphabet)? (a) U (b) V (c) W (d) Y.
7. Silebu meloo lo wa ninu ‘Baba’ (How many syllable(s) are in 'Baba')? (a) meta (3) (b) merin
(4) (c) meji (2) (d)okan (1).
8. A le ri silebu________ ninu oro yii 'Ibepe' (How many syllable(s) can be found in the word
'ibepe') (a)meta(3) (b) meji (2) (c) okan(1) (d)merin(4)
9. Silebu meloo ni o wa ninu oro yii (How many syllable(s) are in the word) 'Ikorodu' ? (a)
meji(2) (b) meta(3) (c) merin(4) (d) okan(1).
10. 'GBA' je oro Yoruba onisilebu_______ (The word 'GBA' has____ syllable(s) (a) mefa(6) (b)
meta(3) (c) okan(1) (d) meji(2).
Choose the right interpretation of the following parts of the body
11. Ejika= (a)hair (b)neck(c) shoulder (d)stomach
12. Ereke = (a)leg (b)shoulder (c)ear (d)cheeks
13. Ika-owo = (a)leg (b)neck (c)head (d)finger
14. Imu= (a) head (b)breast (c)nose (d)hand
15. Ese= (a)leg (b)shoulder (c)knee (d)navel
16. Batani ihun fun ‘Ebun’ ni (a) K-KF (b) F-KFn (c) F-KF (D)KF-KF
17. ‘Osogbo’ (a) F-F-F (b) F-KF-KKF (c) FK-KF (d) F-KF-KF
18. One of these is not a traditional occupation (a) Dokita (b) Agbe (c) Agbede (d) Akope
19. A barber is__ (a) agbe (b) onisowo (c) Onigbajamo (d) akope
20. Awon onilu ni a tun mo si___ (a drummer is refered to as __) (a) ilu (b) kongo (c) ayan (d)
onijo
Ki ni oruko awon eranko yii ni ede Yoruba(what are these animals called in Yoruba)
21. Elephant (a) aja (b) ekun (c) agbo (d) erin
22. Leopard (a) amotekun (b) ekun (c) ewure (d) ejo
23. Snake (a) ejo (b) obo (c) aja (d) igbin
24. Monkey (a) Obo (b) okere (c) kinnun (d) ejola
25. Lion (a) erinmi (b) Kinniun (c) eja (d) kolokolo
26 ____ ni o ko ewi ‘mura sise’ (who wrote the poem ‘mura sise’?) (a) D.O F agunwa (b) J.F
Odunjo (c) A.O Ojo (d) W.F Kumuyi
27. ____ ni oogun ise (a) ere (b) ija (c)ekun (d) ise
28. Isori oro wo ni ’Amusan’ (which part of speech is ‘Amusan’?) (a) oro aponle (b) oro ise (c)
oro oruko (d) oro- atokun
29. One of the following is not a part of speech in Yoruba language (a) oro enu (b) oro aropo
oruko (b) oro apejuwe (c) oro asopo (d) oro ise
30. Okan ninu awon wonyii je apeere eranko omi(which of this is an animal that lives in water)
(a) akan (b) pepeye (c) adiye (d) olongbo
Ki ni a n pe awon owo ile wa wonyii ni ede Yoruba?
31. 50 kobo = (a)ogun kobo (b)Ogbon kobo(c)Aadota kobo (d)Ogoji kobo
32. 25kobo = (a)ogun kobo (b)Aadota kobo (c)Ogoji kobo (d) kobo maarundinlogbon
33. 10 kobo = (a)kobo marun-un (b)kobo meerin (c)kobo mefa (d)kobo mewa
34. 8kobo = (a)kobo meta(b)kobo marun-un (c)kobo mejo (d)kobo merinla
35. 30 kobo (a)ogbon kobo (b) ogoji kobo (c)Aadota kobo (d) ogorun-un kobo
Bawo ni a se n pe awon owo ile wa wonyii
36. Naira mesan-an (a)N20.00 (b)N5.00 (c)N10.00 (d)N9.00
37. Ogoji Naira (a)N30.00 (b)N40.00 (c)N18.00 (d)N35.00
38. Naira mefa(a)N2.00 (b)N4.00 (c)N6.00 (d)N27.00
39. Aadota Naira (a)N50.00 (b)N30.00 (c)N35.00 (d)N10.00
40. Ogbon Naira (a)N15.00 (b)N22.00 (c)N20.00 (d)N30.00
41. Riddle is known as (a)ijo (b)alo apamo (c) orin (d) alo apagbe
42. Folktales ni (a)alo apagbe (b)alo apamo (c) orin (d) ijo
43. Proverb means (a) alo (b) orin (c)owe (d) ijo
Identify the yoruba greeting for each of the period of time written below.
44. Morning= (a)E kaasan (b)E kaaaro (c)E ku irole (d)O dabo
45. Afternoon= (a)E kuirole (b)E kaasan (c)E kaale (d)E kaaa
46. Evening = (a) E kaale (b)E ku irole (c)E ku iyaleta (d)O daroo
47. Welcome = (a)E kaabo (b)o dabo (c)E kaasan d)E ku irole
48. Awon ojo meloo lo wa ninu ose? (a) Mefa (b) Mesan-an (c) Meje (d) Marun-un
49. Tuesday is (a) Aiku (b) Isegun (c) Ojoru (d) Abameta
50. Monday is (a) Isegun (b)Aiku (c) Ojoru (d) Aje
51. Saturday ni a n pe ni (a) Ojo ru (b) Aiku (c) Abameta (d) Aje
52. The day after Saturday is called (a) Aje (b) Abameta (c) Aiku (d) Isegun
53. Dry season ni a n pe ni(a)Igba ojo (b) igba eerun (c) Igba oye (d)Igba ooru
54. Harmmatan period ni a n pe ni(a)igba ooru (b)Igba ojo (c)Igba oda (d)Igba oye
55. It is always sunny during (a)igba ojo (b)Igba eerun (c)Igba oda (d)igba oye
56. Minutes is refers to as (a) wakati (c) aaya (c) iseju (d) Osu
57. Ose ni a n pe ni (a) day (b) month (c) week (d) year
58. Wakati is known as (a) day (b) week (c) year (d) hour
59. Month is called (a) odun (b) osu (c)ose (d)ojo
60. Year is called (a)odun (b)osu (c)ose (d)ojo

Abala keji/Section B.
Dahun eyokan ninu awon ibeere ni abala yii.
(Answer only ONE question in this section)
1. (A) Ko awon oro oni-silebu kan marun-un (Write five one- syllable words that you
know)
(B) Ko oro oni-silebu meji marun-un ti o ranti (Write five two-syllable words that you
can remember).
2. (A) Kin ni a n pe eso wonyii ni ede Yoruba. (What are the Yoruba names of the
following fruits)
(I.) orange (ii.) pawpaw (iii.) pineapple (iv.) banana (v) guava 5 MARKS.
(B) What is the English equivalent of the following words:
(i) akekoo (ii) gege (iii) tabili (iv) patako ikowe (v) aga
SECTION C: Answer only TWO questions
3. Ko osu marun un ninu osu mejila ti a ni. (Write 5 out of the twelve months that we have in a
year).
4. If 2 kobo x 2 kobo = kobo merin, then use the same method to answer the following
(i) 2 kobo x 3 kobo (ii) 5 kobo x 4 kobo (iii) 5 kobo x 5 kobo (iv) 5 kobo x 3 kobo (v) 4
kobo x 6 kobo
5. What are these seasons called in Yoruba?

i. Harmattan ii. Period of draught iii. Rainy season iv. Dry season v. Cold weather 5 MARKS.
MARKING GUIDE:
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10
A C D C C B C A C C
11 12 13 14 15 16 17 18 19 20
A D D C A B D A C C
21 22 23 24 25 26 27 28 29 30
D A A A B B D C A A
31 32 33 34 35 36 37 38 39 40
C D D C A D B C A D
41 42 43 44 45 46 47 48 49 50
B A C B B B A C B D
51 52 53 54 55 56 57 58 59 60
C C B D B C C D B A

1. (A) i. gbe
ii.fe
iii.so
iv.lo
v.ba
(B) i.baba
ii.sare
iii.subu
iv.omo
v.iya
2. (A) i.osan
ii.ibepe
iii.opeoyinbo
iv.ogede
v.gurofa
(B) i.student
ii.pen/biro
iii.table
iv.board:chalkboard,whiteboard
v.chair
3. i.sere
ii.erele
iii.erena
iv.igbe
v.ebibi
vi.okudu
vii.agemo
viii.ogun
ix.owewe
x.owara
xi.belu
xii.ope
4. i. 2kobo x 3kobo= kobo mefa
ii.5kobo x 4kobo= ogun kobo
iii.5kobo x 5kobo= kobo marundinlogbon
iv.5kobo x 3kobo=kobo marundinlogun
v.4kobo x 6kobo= kobo merinlelogun
5. i. Harmattan= igba oye ii. Period of draught=igba erun iii. Rainy season= igba ojo iv. Dry
season= igba erun v. Cold weather= igba otutu

You might also like