[go: up one dir, main page]

Jump to content

Ibn Battuta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abu Abdullah Muhammad Ibn Abdullah Al Lawati Al Tanji Ibn Battuta
OrúkọAbu Abdullah Muhammad Ibn Abdullah Al Lawati Al Tanji Ibn Battuta
ÌbíFebruary, 1304 Tangier, Morocco
Aláìsí1368 or 1369 Morocco
ÌgbàMedieval era
AgbègbèIslamic scholar/Explorer
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Sunni Maliki

Abu Abdullah Muhammad Ibn Abdullah Al Lawati Al Tanji Ibn Battuta (Lárúbáwá: أبو عبد الله محمد ابن عبد الله اللواتي الطنجي بن بطوطة‎), tabi lasan bi Ibn Battuta (February 24, 1304–1368 tabi 1369), je omowe, onirinajo musulumi Beriberi ara Moroko to gbajumo nitori akoole awon irinajo ati irinkerindo re to n je Rihla (ajo ni Arabiki). Awon irinajo re wonyi je fun ogbon odun won si je lori bi gbogbo ile imale ati ju be lo, won lo lati Ariwa Afrika, Iwoorun Afrika, Apaguusu Europe ati Apailaorun Europe, de Arin Ilaorun, orileabe India, Arin Asia, Guusuilaorun Asia ati Saina ni Ilaorun, ijinna to ju awon tosiwaju ati Marco Polo lo. Nitori awon akoole irinajo re wonyi Ibn Battuta je ikan ninu awon arinrinajo olokikijulo.[1]


  1. Nehru, Jawaharlal (1989). Glimpses of World History. Oxford University Press. pp. 752. ISBN 0195613236.  After outlining the extensive route of Ibn Battuta's Journey, Nehru notes: "This is a record of travel which is rare enough today with our many conveniences.... In any event, Ibn Battuta must be amongst the great travellers of all time."