Vanessa Redgrave
Ìrísí
Dame Vanessa Redgrave Order of the British Empire | |
---|---|
Redgrave at the 2016 Cannes Film Festival | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kínní 1937 Blackheath, London |
Ẹ̀kọ́ | The Alice Ottley School]], Worcester, England |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Royal Central School of Speech and Drama |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1958–present |
Notable work | List of Vanessa Redgrave performances |
Olólùfẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ | Timothy Dalton (1971–1986) |
Àwọn ọmọ |
|
Parent(s) |
|
Ẹbí | Redgrave family |
Awards | List of awards and nominations received by Vanessa Redgrave |
Vanessa Redgrave je ọmọ óṣèrè lọkunrin Sir Michael Regrave ati óṣèrè lobinrin Rachel Kempson ti a bini ọjọ ọgbọn óṣu January ni ọdun 1937[1]. Arabinrin naa jẹ osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[2].
Igbesi Aye Arabinrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Vanessa kẹkọ ni ilè iwè tadalẹ fun awọn ọmọ obinrin; Ile ẹkọ Alice Ottley ni Worcester ati Ilẹ ẹkọ Queen's Gate.Vanessa wọ ile iwe sisọ ọrọ ati drama ni ọdun 1954. Óṣere lobinrin naa kọkọ jade si òju èrè West End fun igba akọkọ ni ni ọdun 1958[3]. Óṣere naa fẹ adari ere Tony Richardson lati 1962 ti wọn si bi ọmọbinrin meji; Natasha ati Joely to di óṣèrè lobinrin[4]. Vanessa ati Ruchardson pinya ni ọdun 1967.
Ami Ẹyẹ ati Idani lọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Vanessa gba ami ẹyẹ telivision academy ti british, ami ẹyẹ Golden Globe ati ami ẹyẹ meji ti Primetime Emmy[5][6].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://en.geneastar.org/genealogy/redgravev/vanessa-redgrave
- ↑ https://edition.cnn.com/2013/06/25/world/europe/vanessa-redgrave-fast-facts/index.html
- ↑ https://www.londontheatre.co.uk/stars-on-stage/vanessa-redgrave
- ↑ http://www.oocities.org/hollywood/film/7518/Vanessa/Vanessa.htm
- ↑ https://www.bbc.com/news/entertainment-arts-59780013
- ↑ https://www.bafta.org/media-centre/press-releases/vanessa-redgrave-to-receive-fellowship