Rio de Janeiro
Ìrísí
Rio de Janeiro | |||
---|---|---|---|
Municipality | |||
The Municipality of São Sebastião do Rio de Janeiro | |||
| |||
Nickname(s): Cidade Maravilhosa ("The Marvellous City") or simply, Rio | |||
Location in the State of Rio de Janeiro | |||
Country | Brazil | ||
Region | Southeast | ||
State | Rio de Janeiro | ||
Founded | March 1, 1565 | ||
Government | |||
• Mayor | Eduardo Paes (PMDB) (2009–2012) | ||
Area | |||
• Municipality | Àdàkọ:Infobox settlement/metric/mag | ||
Elevation | from 0 to 1,021 m (from 0 to 3,349 ft) | ||
Population (2008) | |||
• Municipality | 6,093,472 (2nd) | ||
• Density | 4,781/km2 (12,380/sq mi) | ||
• Metro | 14,387,000 | ||
Time zone | UTC-3 (BST) | ||
• Summer (DST) | UTC-2 (BDT) | ||
Postal Code | 20000-000 | ||
Area code(s) | 21 | ||
HDI (2000) | 0.842 – high | ||
Website | City of Rio de Janeiro |
Rio de Janeiro ("Odo January", Pípè: /ˈriːoʊ dɪ ʒəˈnɛəroʊ/; Pípè ni Potogí: [ˈxiu dʒi ʒaˈneiɾu]) je oluilu Ipinle Rio de Janeiro, ilu to tobijulo keji ni ile Brasil ati agbegbe ilu to tobijulo keta ni Guusu Amerika.[1][2][3] Rio de Janeiro ti je oluilu Brasil fun bi ogorun meji lati 1763 titi di 1822 ni igba imunisin awon ara Portugal, ati nigbati Brasil di ominira ni 1822 titi di 1960. O tun je oluilu ti tele fun Ile-Oba Portugal (1808–1821). O gbajumo gege bi "Rio" ni soki, alaje re ni A Cidade Maravilhosa, tabi "Ilu Alara".
Coordinates: 22°54′S 43°14′W / 22.900°S 43.233°W
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ R.L. Forstall, R.P. Greene, and J.B. Pick, "Which are the largest? Why published populations for major world urban areas vary so greatly" Archived 2010-05-31 at the Wayback Machine., City Futures Conference, (University of Illinois at Chicago, July 2004) – Table 5 (p.34)
- ↑ UN list of largest agglomerations Archived 2009-12-23 at the Wayback Machine. The United Nations. Retrieved 30 July 2009.
- ↑ City Population agglomeration list. City Population. Retrieved 30 July 2009.