[go: up one dir, main page]

Jump to content

Rafael Nadal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rafael Nadal
Nadal in 2016
OrúkọRafael Nadal Parera
Orílẹ̀-èdè Spéìn
IbùgbéManacor, Balearic Islands, Spain
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Kẹfà 1986 (1986-06-03) (ọmọ ọdún 38)
Manacor, Balearic Islands, Spain
Ìga1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2001
Ọwọ́ ìgbáyòLeft-handed (two-handed backhand), born right-handed
Olùkọ́niToni Nadal (1990–2017)[1]
Francisco Roig (2005–)[2]
Carlos Moyá (2016–)[3]
Ẹ̀bùn owóUS$90,641,902
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tìrafaelnadal.com
Ẹnìkan
Iye ìdíje867–183 (82.57%)
Iye ife-ẹ̀yẹ75 (5th in the Open Era)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (18 August 2008)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 1 (25 September 2017)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2009)
Open FránsìW (2005, 2006, 2007, 2008, 2010, 2011, 2012, 2013, 2014, 2017)
WimbledonW (2008, 2010)
Open Amẹ́ríkàW (2010, 2013, 2017)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPF (2010, 2013)
Ìdíje ÒlímpíkìW (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje131–72
Iye ife-ẹ̀yẹ11
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 26 (8 August 2005)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 560 (9 October 2017)[4]
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà3R (2004, 2005)
Wimbledon2R (2005)
Open Amẹ́ríkàSF (2004)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje ÒlímpíkìW (2016)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Davis CupW (2004, 2008, 2009, 2011)
Last updated on: Àdàkọ:Date.

Rafael "Rafa" Nadal Parera (Catalan: [rəˈfɛɫ nəˈðaɫ pəˈɾeɾə]; Spanish: [rafaˈel naˈðal paˈɾeɾa]) (ojoibi 3 June 1986) je omo Spani agba tenis alagbase to wa ni ipo kinni lagbaye. Nadal ti gba ife eye awon enikan Grand Slam mejo, eso wura 2008 Olympiki fun awon enikan, o ni record 18 fun awon idije ATP World Tour Masters 1000 o si tun je ara egbe Ife Eye Davis Spein to bori opin idije ni 2004, 2008 ati 2009. O je gbigba bi ikan ninu awon agba tenis to lokiki julo laye.