Promise Amukamara
No. 10 – Charnay BB | ||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Position | Point guard | |||||||||
League | LFB | |||||||||
Personal information | ||||||||||
Born | 22 Oṣù Kẹfà 1993 New Jersey, United States | |||||||||
Nationality | American / Nigerian | |||||||||
Listed height | 1.75 m (5 ft 9 in) | |||||||||
Career information | ||||||||||
High school | Apollo (Glendale, Arizona) | |||||||||
College | Arizona State (2011–2015) | |||||||||
NBA draft | 2015 / Round: 3 / Pick: 36k overall | |||||||||
Selected by the Phoenix Mercury | ||||||||||
Medals
|
Promise Amukamara (born 22 June 1993) is a Nigerian-American basketball player for Charnay Basket Bourgogne SUD (FRA) and the Nigerian national team.[1]
Promise Amukamara tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kẹfà ọdún 1993 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà-Amẹrika fún Charnay Basket Bourgogne SUD (FRA) àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède Nàìjíríà .
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Promise ga ní ẹsẹ̀ bàtà marun ó lé inch mẹsan(175 cm).[2] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti ilé-ìwé gíga ti Arizona University [3]. Ó tún jẹ́ àbúrò fún Super Bowl XLVI Champion, New York Giants tẹ́lẹ̀ rí cornerback Prince Amukamara .
Iṣẹ́ tí ó yàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Promise jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ D'Tigress, ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n obìnrin ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà. Ó jẹ́ olùsọ́ ààyè ti ẹgbẹ́ tí ó ṣeré níbi 2020 Olympic Gamesní Tokyo.[4][5] Ó tún kópa níbi FIBA Women's Basketball World Cup ti ọdún 2018.[6]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- O jú àmì mẹwa fún eré kọ̀ọ̀kan ní Tokyo, ní ọdún 2020
- Akẹkọọ̀ jade akọ̀kọ̀ ní ilé ìwé gíga Arizona State University tí ó jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n obìnrin tí ó kájú láti ṣe ẹgbẹ́ Olympic
- Ọmọ ẹgbẹ́ 2019 FIBA African Championship Gold Medal tí ó kópa nínu Ìdíje ayẹyẹ Pre-Olympic [7]
- agbá bọ́ọ̀lù inú agbọ̀n Arizona ti ọdún 2011 [7]
- Ẹni tí ó yára jùlọ nínú ọgọrún mita àti igba mita gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó sẹ̀sẹ̀ wọ ilé-ìwé gíga [7]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Eurobasket. "Promise Amukamara Player Profile, Charnay Basket Bourgogne SUD, News, Stats - Eurobasket". Eurobasket LLC. Retrieved 2021-05-29.
- ↑ "Promise Amukamara - Player Profile". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-17.
- ↑ Hillman, Jenna; of 2021, ASU Class. "Dribbling to Tokyo: Promise Amukamara Ready to Compete for Nigeria". Arizona State University Athletics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-17.
- ↑ "D'Tigress players lament marginalization, hijack of donations made to team". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-13. Retrieved 2022-05-17.
- ↑ "D'Tigress will make Nigerians proud at Tokyo 2020 — Amukamara". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-04-18. Retrieved 2022-05-17.
- ↑ "Sarah OGOKE at the FIBA Women's Basketball World Cup 2018". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-29.
- ↑ 7.0 7.1 7.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0