Luba
ÀÀYÈ WON
Àríwa iwọ oòrùn Congo (Zaire)
IYE WỌṄ
Mìlíonù kan
ÈDÈ WỌṄ
CILUBE (Ààrin gbùngbùn Bantu)
ALÁBÀÁGBÉ WỌN
Chowe, Ndembu, Kaonde, Benba, Tabwa, Songye, Lunda.
ITAN WỌṄ
Ijọba ńlá Luba ti bẹ̀rẹ̀ ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún kan ààbọ̀ ọdún sẹ́yin 1,500. Ìjọba yìí ń gbòòrò láti Upemba tí Í ṣe ààrin gbuńgbún Lube. Wọn fẹ̀ dé iòkè Tangayika lábẹ́ llnngh Sungu tí í ṣe olorí wọṅ ní 1760-1840. Ó gbòòrò de apá àríwá àtiu gusu ní 1840 lábẹ́ iiungo kablee. Igbà tí olórí yà papòdà ni awọṅ Láíubáwó amúnilérú àti àwọn òyìbó anúnisìn sọ ìjọba ńlá wọn di yẹpẹrẹ.
ÌṢẸ̀LU WỌṄ
Ìjọba àpapọ̀ ni wọṅ ń ṣe Aláyèlúwà (Mulopwe) ni olórí wọn. Awọṅ ìlú kèkerè ń wárì fún Mulopwr. Òun ìlú àti olórí ẹgbẹ́ Bambulye
ỌRỌ̀ AJE WỌN
Iṣẹ òwò iyò àti iru ni àwọṅ ọlọlá wọn tún ń ṣe àgbe iṣẹ ọdẹ ẹran àti ti ẹja tún wó pọ̀ láàrin wọn.
IṢẸ́ ỌNA WỌṄ
Iṣẹ́ agbẹ̀gilére ni iṣẹ] wọn. Ère ló ń ṣègbè fún abọ ni wọṅ ń gbẹ̀. Wọ́n tún ń gbẹ̀ ère àgba tí a mọ̀ sí (Mboko)
Ẹ̀SÌN WỌN
Àwọṅ baba ńlá wọn ni wọṅ ń bọ. Ọba wọṅ gan0an ló ní òriṣà.