[go: up one dir, main page]

Jump to content

Kwame Ture

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kwame Ture
4th Chairman of the Student Nonviolent Coordinating Committee
In office
May 1966 – June 1967
AsíwájúJohn Lewis
Arọ́pòH. Rap Brown
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Stokely Standiford Churchill Carmichael

(1941-06-29)Oṣù Kẹfà 29, 1941
Port of Spain, Trinidad and Tobago
AláìsíNovember 15, 1998(1998-11-15) (ọmọ ọdún 57)
Conakry, Guinea
(Àwọn) olólùfẹ́
Miriam Makeba
(m. 1968; div. 1973)

Marlyatou Barry (divorced)
Àwọn ọmọ2
EducationBronx High School of Science (1960)
Alma materHoward University
(B.A., Philosophy, 1964)

Kwame Ture ( /ˈkwɑːm ˈtʊər/; orúkọ àbísọ Stokely Standiford Churchill Carmichael, June 29, 1941 – November 15, 1998) jẹ́ alákitiyan ará Trínídàd tò kópa nínú ìrìnkankan àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti nínú Pan-African movement|ìrìnkankan Ìṣe Pan-Áfríkà lágbàáyé. Wọ́n bíi ní orílẹ̀-èdè Trinidad, sùgbọ́n ó dàgbà ní Amẹ́ríkà láti ìgbà ọmọ ọdún 11, ó sì di alákitiyan nígbà tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní Yunifásítì Howard.

Kwame Ture