Kalulu
Kalulu | |
---|---|
Kalulu in a suit | |
Ọjọ́ìbí | Ndugu M’Hali c.1865 Africa |
Aláìsí | 28 Oṣù Kẹta 1877 Kalulu Falls lẹ́bàá odò Lualaba |
Cause of death | ìrìlómi |
Ẹ̀kọ́ | fún gbàdíẹ̀ ní Wandsworth |
Ndugu M’Hali tabi Kalulu (c.1865 – 1877) je omo Afrika oniwofa ati omo agbatoju si Henry Morton Stanley. O ku nigba odo sugbon nigba igbesiaye soki re o se abewo lo si Europe, Amerika ati Seychelles. O je yiyesi pelu iwe kan, o je yiyalaworan ni Madame Tussauds bee sini o je alejo nigba isinku Dr Livingstone.[1]
Itan igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]M’Hali je bibi ni Afrika o si di alayanfe Henry Morton Stanley leyin ti won fifun ni Tabora ni Tanzania. Stanley fun ni ominira o si yi oruko re si Kalulu. Oruko re tele ni "Ndugu M’Hali" to tumosi "Arakunrin ore mi".[1] Stanley pe ni Kalulu nitori pe o ro pe o tumoso ọmọ ẹtù sugbon awon miran ti so pe o je ehoro.
Some see their relationship as homosexual but there is no firm evidence.[1] Leyin igba ti Stanley sawari Dr Livingstone o pada si Ilegeesi o si mu Kalulu pelu re.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Colonialism and homosexuality p.43-44, Robert F. Aldrich, 2003, Routledge, accessed July 2010