[go: up one dir, main page]

Jump to content

Dogon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dogon people

Dogon people, Mali
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
400,000 to 800,000
Regions with significant populations
Mali[1]
Burkina Faso[2]
Èdè

Dogon languages

Dogon Àwọn ènìyàn bíi ìdajì mílíọ̀nù tí a bá pàdé ní ilẹ̀ Mali àti Burkina Faso ni wọ́n n sọ èdè yìí. Bendor-Samuel àti àwọn ìyókù (1989) ni ó gbé àtẹ yìí kalẹ̀. Ínú àtẹ yìí, a rí ‘Proto Dogon’ ti o pín ṣi ìsọ̀rí mẹfa. Àwọn ìsọ̀rí náà nìwọ̀n yìí

(a) Plain - Jamsay tegu, Toro teju, Tene ka, Tomo ka

(b) Escarpment Toro sọọ, Tombaco sọọ, Kamba sọọ

(d) West - Dulerí dom, Ẹjẹngẹ dó

(e) North west - Bangeri Me

(ẹ) North Platean - Bondum dom. Dogul dom

(f) Ìsọ̀rí kẹfà ni Yanda dom, Oru yille àti Naya tegu.

Iye àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ 100,000. (Ọ̀kẹ́márùn-ún) Orílẹ̀ èdè tí wọn tí ń sọ èdè yìí ni Mali, ati Burkina Faso