[go: up one dir, main page]

Jump to content

Àròjinlẹ̀ aláyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìròjinlẹ̀ oníàgbéwò tabi irojinle alagbewo je idanwo ati ayewo awujo ati asa, nipa lilo imo inu awon sayensi awujo ati awon sayensi omoniyan. Oro yi ni itumo meji pelu awo orisun otooto ati itan: ikan bere lati inu oro-awujo ekeji lati inu iseagbewo onimookomooka. Eyi lo fa to je pe This has led to the very literal use of 'irojinle alagbewo' to ka si gbogbo irojinle to ba duro lori ayewo.

Ninu lilo oloro-awujo, irojinle alagbewo untoka si iru irojinle Marksisti pelu agbara lati koju awon ipa alaise Marksisti (fun apere iwe Friedrich Nietzsche ati Sigmund Freud).[1] Agbara yi ni awon asemarksisti gbamugbamu unpe bi abuku ni 'iseatunyewo'. Irojinle alagbewo odeoni dide lati inu eka to ta wa lati inu oro-awujo alaiseonididaloju ti Max Weber ati Georg Simmel, irojinle Marksisti tonituntun ti Georg Lukács ati Antonio Gramsci, titi de ti awon to sepo mo Ibi-Eko Iwadi Awujo Frankfurt.

Pelu awon aserojinle ibi ti aun pe ni '"Ile-Eko Frankfurt" ni oro yi unsaba toka si: Herbert Marcuse, Theodor Adorno, Max Horkheimer, Walter Benjamin, ati Jürgen Habermas. Latowo eni to gbeyin yi ni irojinle oniagbewo ti tun jinna si ibere to ni ninu iseboseye Jemani to si bo sunmo iseoloungidi ara Amerika. Fife wa idi onirojinle fun "opo titobi" asa to wa lati "ipile" eleroja nikan ni igbagbo Marksisti toseku ninu irojinle alagbewo igbalode.[2]


  1. Outhwaite, William. 1988. Habermas: Key Contemporary Thinkers 2nd Edition (2009). p5. ISBN 9780745643281
  2. Outhwaite, William. 1988. Habermas: Key Contemporary Thinkers 2nd Edition (2009), p.5-8 (ISBN 9780745643281)