Oriki Olodumare Olorun
Oriki Olodumare Olorun
Oriki Olodumare Olorun
Olugbala,(Our saviour)
Olutusile,(God of freedom)
Oludariji,(Our forgiver)
Oba to segun agbara ese, (God who delivers from hold of sin)
Oba to san gbogbo gbese wa,(God who pays the price for our sins)
Olorun ajinde,(The resurrected Lord)
Olutunu,(Our comforter)
Olufe okan wa,(My lover)
Oba to yan wa fe,(God who has predestined us)
Olusegun,(The conqueror)
Ajasegun, (The conqueror
Gbanigbani nijo ogun le,(Our defense in time of war)
Ogbagba ti ngbara adugbo,( The Protector)
Oba to pin okun pupa niya,( God who parted the red sea)
Olorun to mu Jodani sa niwaju awon omo Re, (God who parted the river Jord=n)
Oba to bi odi Jeriko wo,(God who fell down the walls of Jericho)
Olorun to kolu Egipiti lara awon akobi re,(God who killed the first born=of the Egyptians)
Oba to ju gbogbo orisa lo,(The almighty God)
Olorun to tobi ju gbogbo aye lo,(Greater than all the earth)
Oba to da monamona fun ojo, The God who created lightening for the rain)
Aimope ani oje,
Oba to jewe ategbo lo,
Oba to ni owa towa,(The God who commands)
Oba toni olo, tolo, (The God who commands)
Oba toni kowa, towa, (The God who commands)
Oba toni komasi, ti o si si mo,(The God who can close a door and no man=can open)
Oba tao ri, sugbon tari ise owo Re,(The unseen God but we can feel his=impact)
Olorun to n gbo adura, (God who hears prayers)
Oba to n dahun adura, (Prayer answering God)
Olorun tape to n je,(The God that you can call and he will answer)
Oba to n dahun adura pelu ina,(God that answered by fire)
Eleda,(Creator)
Iye,(Resurrection)
Aduro gboingboin lehin asotito,(Defender of the Truthful)
Imole ninu okunkun aye,(The light in darkness)
Alagbara lorun ati laye,(Mighty in heaven and on the earth)
Oba ti nyoni kuro ninu ofin aye,(God who rescues from the dungeon)
Atofarati,(Our defense)
Atogbokanle,(The trustworthy God)
Atofokante,(Our Confidant)
Adunbarin,(Worthy to walk with)
Adunbalo, (Worthy to follow)
Adunkepe,(God you can call on)
Apata ayeraye,(The rock of ages)
Atobiju,(The Almighty)
Atofarati bi oke,(Our support and defense)
Apata wa,(Our rock of Ages)
Odi wa,(Our shield)
Alabarin aye wa, (Our companion)
Olupese,(Our provider)
Olugbega,(The lifter of our head)
Oluranlowo,(Our help)
Ireti wa,(Our hope)
Olu aye,(God on earth)
Olu orun,(God in heaven)
Oba ti gbobo oba ntowo Re gbase,(Kings from whom kings take directives)
Adakedajo, (He who Judges silently)
Adajo ma fi tenikan se,(The just Judge)
Oba ti kii sojusaju,(The just God)
Oba tenikan o le pe lejo,(The king that can not be judged)
Oba aseyiowu,(Unquestionable God)
Oba tii sagan dolomo,(The god who opens the womb of the barren)
Abiyamo ode orun,(The great mother of heaven)
Atorise,(God who can turn bad situation to good)
Asoloriburuku dolorire,(God who can remove the inadequacies from ones li=e)
Arinu rode,(God who sees the visible an the invisible,)
Olumoranokan eda, (He who sees the intent of the heart of man)
Oludamoran (The Great adviser)
Baba wa,(Abba father)
Ore wa,(Our friend)
Ibi isadi wa,((Our refugee)
Aabo wa,(our protector)
Oluwosan,(the healer)
Asoku dalaye,(He who brings the dead to life)
Olorun alaaye,(God of the living)
Oba ti n pojo iku da,(God who can change appointment with death)
Oba ti emi gbogbo enia wa lowo Re,( He who has the keys to our existence)
Oba ti nti tenikan o lesi,(He who shuts and no one can open)
Oba ti nsi tenikan o leti,(He who opens and no one can close)
Awamaridi,(Unsearchable God)
Eleruniyin,
Abetilukara bi ajere,(God who is all ears)
Aiku,(Living God)
Aisa,(Faithful)
Oba ti ki sun, ti ki togbe (The king that neither sleeps nor slumbers)
Oba onise nla,(The great worker of good)
Onigbonwo wa, (Our sponsor)
Olorun pipe,(Perfect God)
Olorun rere,(Good God)
Akiri sore,(He who goes about doing good)
Asore kiiri, ,(He who goes about doing good)
Gbongbo idile Jesse,(The root of the tribe of Jesse)
Oba to foro da ile aye,(He that created all things by his spoken word)
Oba to ti wa kaye o towa,(He who was in existence before creation)
Oba ti o ma wa nigba taye o ni si mo,(He who will remain at the end of al= things)
Oloruko nla,(The great name)