Ado Gwanja
Olórin àti òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Ado Isah Gwanja (tí wọ́n bí ní 22 January 1990) jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti òṣèrékùnrin nínú àwọn fíìmù àgbéléwò ti apa Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà.[2][3]
Ado Gwanja | |
---|---|
Ado Isah Gwanja | |
Ọjọ́ìbí | Ado Isah Gwanja 22 Oṣù Kínní 1990 Kano |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Federal College of Education Kano |
Iṣẹ́ | Singer, Film Producer and Film Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2017-Present |
Gbajúmọ̀ fún | Musicians |
Àwọn ọmọ | 1 daughter[1] |
Awards | Get Kano award Best Actor, Sani Abacha Youth Center Award Best Hausa artists Rhymes Pillars Crew |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ado Gwanja na cikin wasa a Legas aka shaida masa matarsa ta haihu". 22 August 2019.
- ↑ "Ni ba dan daudu ba ne – Ado Gwanja". BBC News Hausa (in Èdè Hausa). 18 November 2021. Retrieved 27 April 2022.
- ↑ Admin (14 March 2022). "CIKAKKEN TARIHIN ADO GWANJA - Northernwiki Mawaka". Northernwiki (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 May 2023. Retrieved 24 April 2022.