UNA HISTORIA DE DAISY
IYALẹNU NAA
LA SORPRESA THE SURPRISE
Deesi gbé foonu ó si Daisy cogió el teléfono e intentó Daisy picked up the telephone
gbiyanju lati tun pè oníbàárà ponerse en contacto de nuevo and tried to get through to her
rẹ leekan si. client again.
con su cliente.
Oníbàárà rẹ, ni Franki Su cliente, un tal Frank Baccini, Her client, a certain Frank
Baksini kan bayii, ti o ní ilé- que tenía un almacén de Baccini, who had a warehouse of
ẹru nla kan fun awọn ohun electrical goods, had not paid for
èlò-ina, kò tii sanwó fun ise
electrodomésticos, no le había
pagado por sus dos días de her two days' work.
ọjọ méjì ti oun se fun un.
trabajo.
Deesi ti tiraka lati se awari Daisy había descubierto dónde Daisy had managed to discover
ibi ti alailootọ ẹnikeji Ọgbẹni estaba viviendo el socio where Mr. Baccini's dishonest
Baksini n gbé bayii o sì n fi partner was now living and was
taratara reti sọwedowo rẹ.
deshonesto del Sr. Baccini y
estaba esperando ansiosamente anxiously expecting her cheque.
el cheque.
Deesi ti bẹrẹ si ni rò o pé Daisy estaba empezando a Daisy was beginning to think that
àfàìmọ ki Oníbàárà oun pẹlu pensar que su cliente era también her client was dishonest too.
naa má jẹ alaisootọ.
deshonesto.
Ohun kan bi ẹni ti nnkan sú, Un aburrido "Hola, ¿puedo A very bored "Hello, can I help
dáhùn ni odikeji foonu, hacer algo por usted?" fue la you?" was the reply at the other
“Hẹlo, ki ni ẹ fẹ?”
respuesta desde el otro lado de la end.
línea.
Ohùn ọdọbínrin kan tii se Era la voz de una mujer joven, la It was a young woman's voice,
akọwe Franki Baksini ni. secretaria de Frank Baccini. Frank Baccini's secretary.
“Jọwọ, mo fẹ ba Ọgbẹni "Me gustaría hablar con el Sr. "I'd like to speak to Mr. Baccini,
Baksini sọrọ,” Baccini, por favor." please."
“E má bínú o, Ọgbẹni Baksini "Lo siento, el Sr. Baccini está "Sorry, Mr. Baccini is out of
kò si ni ilé.” fuera de la ciudad." town."
Deesi takú, o ni “amọ, igba "¿Cuándo volverá?" insistió "But when is he coming back?"
wo ni yoo padà dé? Daisy. insisted Daisy.
“Emi kò mọ o” "Me temo que no lo sé." "I'm afraid I don't know."
“N jẹ o le sọ fun un pé Deesi "¿Podría decirle que ha llamado "Will you tell him Daisy Hamilton
Hamitin pè e sori aago maa Daisy Hamilton y que me telephoned and would like to talk
sì fẹ lati ba a sọrọ ni gustaría hablar con él to him urgently."
kánkán.”
urgentemente?."
“Kò burú, ó dara mo rò bẹẹ” "Bueno - sí, me imagino que sí", "Well - yes, I suppose so," was
ni gbogbo èsì kò-kàn-mi ti ó fue la desconcertante respuesta. the completely unconcerned
fun un. reply.
Eyi ni ìpè sorí foonu Era la décima vez que Daisy This was the tenth telephone
ẹlẹkẹwaa ti Deesi maa ni hablaba con esta joven en dos conversation Daisy had had in
laarin ọsẹ meji pelu ọdọbínrin two weeks with this young
yii, sugbon Franki Baksini kò
semanas, pero Frank Baccini no
se había puesto en contacto con woman, but Frank Baccini hadn't
tii kàn si i paapaa.
got in touch with her yet.
ella todavía.
Inu bi Deesi, o si pinnu lati lọ Daisy estaba furiosa y decidió ir Daisy was furious and decided to
si ile-ẹru Ọgbẹni Baksini ki al almacén del Sr. Baccini para go to Mr. Baccini's warehouse to
oun lè mọ ti ó bá wà nibẹ. see if he was there.
ver si estaba allí.
Nigbati ó dé ibẹ, o kàn ilẹkun Cuando llegó, llamó a la puerta When she arrived, she knocked
ọọfisi naa. de la oficina. on the office door.
Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ, La secretaria del Sr. Baccini Mr. Baccini's secretary said in
Akọwe Baksini wi pe, “Wọle contestó con su monótona voz: her monotonous voice: "Come
wá.” in."
"Pase".
“Mo ti pè sori aago ni "He llamado muchas veces - mi "I've telephoned many times - my
aimoye igba – emi ni Deesi nombre es Daisy Hamilton". name is Daisy Hamilton."
Hamitin.”
“Lootọ? Tani o fẹ ba ni "¿De verdad? ¿Con quién desea "Really? Who did you want to
gbolohun?” ọdọbinrin naa hablar?" Contestó la joven sin ni speak to?" asked the young
beere lai tilẹ bojuwo Deesi. woman without even glancing at
siquiera mirar a Daisy.
Daisy.
Deesi fèsì pé, “Ọgbẹni "Quiero hablar con el Sr. "I want to speak to Mr. Baccini,"
Baksini ni mo fẹ ba ni Baccini," contestó Daisy. replied Daisy.
gbolohun.
Kódà ó tilẹ ti mura ìjà sí i. Estaba poniéndose más y más She was becoming even more
agresiva por momentos. aggressive.
Pelu ohun ma-yọ-mi-lẹnu rẹ "Me temo que no se encuentra "I'm afraid he's not here," said
naa, o wi pe, “Ko si ni ibi o.” aquí", contestó la secretaria con the secretary in her usual
Ó sì tun n kà iwe-irohin rẹ lọ. monotonous way and went on
su acostumbrado tono monótono,
y siguió leyendo la revista. reading her magazine.
Deesi wi pelu ariwo pe, “Ó tó Daisy gritó "¡Ya está bien!" y dio Daisy shouted "Enough is
gẹẹ bayii”, ó sọ ilẹkun gbà-à. un portazo al salir. enough!" and banged the door
closed.
Ọkàn Deesi kaarẹ lọpọlọpọ. Daisy estaba bastante deprimida. Daisy felt rather depressed.
“Mo mọ ohun ti maa se,” "Ya sé lo que voy a hacer," "I know what I'll do," she thought,
Maa fẹsẹ kan duro ni isọ pensó, "me pararé en Luigi´s "I'll stop off at Luigi's for a nice
Luigi fun kétíya ọlọgẹdẹ kan banana split."
para tomarme un sabroso
ti o dọsọ.
banana split."
Deesi fẹran lati maa jokoo si A Daisy le gustaba sentarse en la Daisy liked sitting in Luigi's ice-
isọ kétíya Luigi, ki ó sì heladería de Luigi y charlar un cream parlour and having a little
takurọsọ diẹ pẹlu onisọ yii, ti chat with the owner, a positive-
poco con el dueño, un italiano
ó jẹ ara Itali kan ti ki i se thinking Italian.
elérò buburu optimista.
Bi Deesi se mú òkè gùn lọ si Cuando Daisy subió las As Daisy walked up the stairs to
ọọfisi rẹ, ọrọ ti o jẹ mọ awon escaleras de su oficina se sentía her office she felt a little less
ọmọ eniyan kò dùn un mọ.
un poco menos decepcionada por sore about human beings.
la humanidad.
Bi Deesi se n paarọ bàtà rẹ Cuando Daisy estaba Just as Daisy was changing her
lọwọ sí sálúbàtà, bẹẹ ni cambiándose los zapatos por un shoes to a more comfortable
ẹnikan kàn ilẹkun ti ó si wọle pair, someone knocked on the
par más cómodo, alguien llamó a
wá. door and walked in.
la puerta y entró.
Onisẹ kan ti ó wọ asọ isẹ Era un trabajador en mono. It was a workman in overalls.
toketilẹ ni
“Omidan, ẹ jọwọ se ẹyin ni "Discúlpeme señorita - ¿Es Vd. "Excuse me miss - are you Miss
Omidan Deesi Hamitin? Nibo la Srta. Daisy Hamilton? ¿Dónde Daisy Hamilton? Where shall we
ni ki a gbé awọn eleyii kalẹ put these?" pointing to two large
ponemos esto?" dijo, señalando
sí?” ó n na ọwọ sí àpótí nla boxes on the landing.
meji ti n bẹ ni idasẹle dos grandes cajas que estaban en
àbágòkè. el rellano.
Bẹẹ ni, emi ni Omidan Deesi "Sí, yo soy Daisy Hamilton pero "Yes, I am Daisy Hamilton but
Hamitin sugbọn ki ni awọn ¿qué tienen ahí? - ¿Qué hay en what have you got there - what's
ohun ti ó wà ninu awọn àpótí in those boxes?"
esas cajas?"
nibẹ yẹn?”
“Ẹrọ amu-nnkan-tutú ni eyi ti "La grande es un frigorífico y la "The big one is a fridge and the
o tobi yii, kekere sì jẹ ẹrọ ti n pequeña una cafetera de smaller one is a cappuccino-
pò ẹlẹrindodo. Awọn ti o yàn making machine. You've chosen
capuchino. Ha elegido bien,
yii dara o, se o mọ, iru awọn well, you know, these are the
ti ó dara jù ni arọwọto ni yii.” ¿sabe? son de las mejores
best makes around."
marcas".
Deesi lọgun pe “Emi ò sọ pe "Yo no he pedido nada de eso," "I haven't ordered either of
mo fẹ rà awọn yii o,” exclamó Daisy. these," exclaimed Daisy.
“Onisẹ fi dandan mu u pe "¡Pero su nombre está en la nota "But it's your name on the
“Sugbọn orukọ rẹ ni n bẹ lori de entrega!" insistió el delivery note!" insisted the
iwe ẹrù!” workman.
trabajador.
“Gbogbo owó ni ó ti wà ni "Está todo pagado - sólo dígame "It's all paid for - just tell me
àsanpé. Sá sọ ibi ti maa gbe donde ponerlos". where to put them."
wọn kalẹ si.”
Ó kù diẹ ki Deesi kọ awọn ẹrù Daisy estaba a punto de rechazar Daisy was just about to refuse
yii nigbati ó ri ti Franki la entrega cuando vio a Frank the goods when she saw Frank
Baksini pẹlu n wọle bọ wá.
Baccini entrando también por la Baccini coming in the door, too.
puerta.
“Omidan Hamitin. Mo tọrọ "Srta. Hamilton. Siento mucho no "Miss Hamilton. I'm very sorry I
aforijin pe mi ò kàn si ọ lati haber estado en contacto. haven't been in touch.
igba yii wá.
“Mo rò pe kò bi ọ ninu, mo ti Espero que no le importe pero I do hope you don't mind but I
sakiyesi pe o ò ni ẹrọ amu- me he enterado de que no tenía had noticed you didn't have a
nnkan-tutú ninu ọọfisi rẹ fridge in your office and... this
frigorífico en su oficina y... esta
ati…… ẹrọ ti n pò ẹlẹrindodo cappuccino-making machine is a
yii jẹ iru eyi ti kò wọpọ. cafetera de capuchino es una
little speciality.
pequeña especialidad de la casa.
“O, tilẹ wò naa, sọwedowo rẹ Ah, por cierto, aquí tiene el Oh, by the way here is your
ni yii fun isẹ ribiribi ti o se, cheque por el estupendo trabajo cheque for the excellent work
pẹlu èènì owó diẹ fun awọn you did, with a little extra for your
que desarrolló, con un pequeño
ìnáwó pẹpẹpẹ rẹ” expenses."
extra por sus gastos."
Franki Baksini ri pe ẹnu ya Frank Baccini vio que Daisy Frank Baccini saw Daisy was
Deesi, ó fi kun ọrọ pe: estaba atónita y añadió: astonished and added:
“Mo lero pe akọwe mi ti maa "Espero que le llamase mi "My secretary did phone you, I
pe ọ? “Mo lọ irin ajo lati bi secretaria. He estado un par de hope? I've been away for a
ọsẹ meloo diẹ lati lọ gbadun couple of weeks on honeymoon."
semanas fuera por mi luna de
pẹlu iyawo mi tuntun.”
miel."
Deesi yara sara rẹ giri, Rara, Daisy se recuperó, "Bueno, no, Daisy recovered herself, "Well,
ko buru, kò pè mi – amọ ko si ella no me dijo nada - ¡pero no no, she didn't - but that's quite all
iyọnu, Ọgbẹni Baksini. right Mr. Baccini!"
se preocupe Sr. Baccini!.